Introduction to oriki Ile Yoruba by Chief Torótoró

Introduction to oriki Ile Yoruba by Chief Torótoró
Introduction to oriki Ile Yoruba by Chief Torótoró

Mo ooooo modé lónìí
Mo dé bí mo ýe e dé ooo
Èmi Àyôolóògún olóhùn arò tí jë Torótoró

Torótoró Ayô olóògún olóhùn arò
Iwin tí körin àràmàÃdà bàbá àwön pèdèpèdè

Moríbá moríbà f’õlõhun öba t’ó dá mi
Bàbá mi baba olórun mi kôkô kín tó kö sáyé ooo
Ìbà àti wáyé öjõ, morí’bà àti wô òòrùn
Ôsán gangan öba mökin
Kùtùkùtù öba ìbò

Móríbà moríbà moríbà moríbà moríbà
Akõdá ayé moríbà moríbà
Ilê ôgërë afökõ yçrí atërçrç kárí ayé
Têsç dèpè nù tí n gbé ni mì ní kàlòkàlò, ìbà

Mo ní bí ömödé bá ti jí
K’ó tètè rí bà f’ágbàlagbà ni
Kó lè roko dö’jõ alë ooo
Fúnlê, ilê yóo sì lanu nii
Àyôfë ògún oko lèmí agbê

Moríbà moribà moríbà orin çnu mi
Kí to máa yç körin
Àyôfë ògún olóhùn arò tí dún lõwõ lõwõ
Torótoró Àyôfë olóhùn àrò ooo
Ìbà àti wáyé öjõ
Moríbà n tó máa löö

More Oriki can be found on the list below

  1. Oriki Awori
  2. Oriki Iwo

By Haba Naija Admin

Temi Odurinde worked in domain name registration and web hosting industry for many years before becoming a web entrepreneur. He is passionate about web and mobile technologies. Temi contribute mainly to Haba Naija Internet and Technology sections. He has a BSc in Computing and Psychology, a postgraduate degree in Internet Technologies. Outside work, he love Oral Storytelling, long distance running and playing Volleyball.