oriki ile yoruba by Torotor
oriki ile yoruba by Torotor
oriki ile yoruba by Torotor

Eulogy to Ile Ife : the people and land

Çê rii lóòní gbogbo ömö kóotúu oò jíire
Níbo lojú rere ti mõ wá ilé ayé oooo
Çê mô péee moní láti ilé-ifë ná-àn ni

Omi lè n’ìyàn a ýàn kiri ni ooo
Kómi tó dàbàtà, kómi tód’odò
Ibì kan l’ógbé sun

Ömô yó’òbá ömö odùduà ilé-ifê lorírun wa
Isu ònítaa kógbàgbé àpárí ooo
Àgbàdo òní yö’mö kó gbàgbé ìrùkêrê
Èmi òní gbàgbé ìran baba tèmi

Gbogbo ömö odù tó dá ìwà
Gbogbo ömö kóotùu oòjíire
Mo fë lö ilé àwôn baba lá bàbá wön têyin ni

Mo fë lö sí’lé, ilé onífê öôni.
Mo ṣe kábíyèsí fún öba Síjúadé

Síjúadé oní’fê öôni, èrò làrë ömö a têye gbè
Mo ýe kábíyèsí nígbà egbèje
Mo sún mõ’ba ní wôn egbèje

Mo jìnà s’õba níwôn çgbêfà
Arõba fín löbaá pa
Mo ní moríbà orin çnu-un mi

Kí n tó máa yç’ta löö
Àyôfë ogún ömö ni’yì yàn’lè yàn’lè
Mo se bë’n gbõ, mose bë’n gbõ
Ohùn çnu tèmi.

A búooooooo onífê öôni
A bú ooooo onífê oòyè

Ömö akájé owó,

Ömö êrùjêjê ni gbogbo ilêkílê

Un òo yê lõwõ hun ò yê lápò ogo

Malawo çdan pêlë ömö alápópó ni póorópó

Êyin ömö onífê öôni

A kìí dú’ó ká kí wön ní’fê öôni

A’kìí bêrê ká kí wön ní’fê oòyè

b’abá dúró kíwön ní’fê wön ìí tó abërë

çbo ni wõn fi’ ní ýe

Mo dú’ó kíwön ní’fê wön ò fimí ýç’bö

Mo bêrê kí wön ní’fê wön ò fimí ýç’bö

Nítorípé ojú rá’bç sá ni baba tèmi

Çê ríi ooo bí’n bá torí oní këkë kú

Wõn a söpé ikú arçwà ló p’ogó

Nbá torí onípêrêsëkú

Wõn á ní ikú arçwà ló p’ogó

Onípêrêsë abilà mërìndínlógún

Ççru b’ërú abilala lënu, gàmbàrí loní rayí àgbà

Moki yín lõnà ìbêhun mo dá le.

Êyin lömö olódò kan o tereéééé

Ömö olódoò kan o tàràrà

Tó ýàn wéréke, tó sàn wérèke

Tó d’éyìnkùlé ösinlè tó d’àbàtà

Asákëkë wõn ti ní ògbödô pönmu

Abàbajà wön ò gbödô bù ýin’sê

Ì sô wun sôbôrô ni yó múmi odò naa gbç

Ålë ömö oní’fê öôni

Ömö olúkön bá n bá tíbá

Ömö onímùkúlù kan o bà bà Ã tibà

Tí n fi awö çkùn sèlù lõjõ ojõsí

Aketepe ‘tí erin ni wõn fín so fun rç

Asëkëkë wõn ti ní ògbödô kò gbödô

Jóo à babàjé ògbödô pásêdà

Ìsôwõòhun sôbôrô o hún ní’yo jólù naa yaa

Ìsôwõòhun sôbôrô ni yóoo jólù naa ya.

Oní, oní, oní’fê öônii ömö akájé owó rç mö

Èrùjêjê ní gbogbo ilêkílê

Àsê mërìndílógún l’oní’fê kàn bí ojúmõ bá ti mõ

Bí wõn bá kêsán inú, wön a tún kêsán tò’de

Oní’fê öôni ömö akájé owó rçmö

Êrùjêjê ní’lê kilê

Bí n bá lö lõnà ibê hun ibi tó lápççrç ni

Àyôfë ògún oko lêmí àgbê

Ifê ni oooo, ifê ni ibi tójúmõ timõwa ifê ni .

Download Oriki Ile Ife by Chief Torotoro

Play audio file online

Download it:
ORÍKÌ IFẸ̀

By Haba Naija Admin

Temi Odurinde worked in domain name registration and web hosting industry for many years before becoming a web entrepreneur. He is passionate about web and mobile technologies. Temi contribute mainly to Haba Naija Internet and Technology sections. He has a BSc in Computing and Psychology, a postgraduate degree in Internet Technologies. Outside work, he love Oral Storytelling, long distance running and playing Volleyball.